Onise Iyanu (Lyrics + Video) – Ruth Oluwadamilola

Ruth Oluwadamilola Songs

 

 

StartNOW

 

Click StartNOW to download:

 

 

ONISE IYANU LYRICS

 

 

CHORUS:

Tani ba fiowe, (Onise Iyanu),

Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),

Koseni tale fi owe, Iwo L’onise Iyanu x2

 

 

SOLO:

Omu aro larada (Onise Iyanu),

Afoju reran (Onise Iyanu),

Aditi Gboro oo (Onise iyanu),

Hes a Mighty God (Onise Iyanu),

Koseni talefiowe, Iwo L’onise Iyanu.

 

 

CHORUS:

Tani ba fiowe, (Onise Iyanu),

Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),

Koseni tale fi owe,

Iwo L’onise Iyanu x2

 

 

SOLO:

Oji oku dide (Onise Iyanu),

Oni Lazaru jade wa (Onise Iyanu),

Koseni tale fi owe,

Iwo L’onise Iyanu

 

 

CHORUS:

Tani ba fiowe, (Onise Iyanu), Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),

Koseni tale fi owe, Iwo L’onise Iyanu x2

 

 

SOLO:

Ekan rin si Oba Ogo,

Iyanu lo lorun wa,

Egbe Oruko Jesu ga,

Agbare wasibe. Jesu to so eru wa dayo,

To mu ibanuje tan. Ori iyin leti eleshe, Iye ati ilera.

 

 

CHORUS:

Tani ba fiowe, (Onise Iyanu), Taniba Fiowe oo, (Onise Iyanu),

Koseni tale fi owe, Iwo L’onise Iyanu x2

 

      -Written By Domzy

 

 

 

Watch Video Below: